Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 93 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَتَقَطَّعُوٓاْ أَمۡرَهُم بَيۡنَهُمۡۖ كُلٌّ إِلَيۡنَا رَٰجِعُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 93]
﴿وتقطعوا أمرهم بينهم كل إلينا راجعون﴾ [الأنبيَاء: 93]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn yẹhudi àti nasara), wọ́n sì dá ọ̀rọ̀ (ẹ̀sìn) wọn sí kélekèle láààrin ara wọn; ẹnì kọ̀ọ̀kan (wọn) sì máa padà sí ọ̀dọ̀ Wa |