Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 98 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿إِنَّكُمۡ وَمَا تَعۡبُدُونَ مِن دُونِ ٱللَّهِ حَصَبُ جَهَنَّمَ أَنتُمۡ لَهَا وَٰرِدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 98]
﴿إنكم وما تعبدون من دون الله حصب جهنم أنتم لها واردون﴾ [الأنبيَاء: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ẹ̀yin àti n̄ǹkan tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún lẹ́yìn Allāhu ni ìkoná Jahanamọ; ẹ̀yin yó sì wọ inú rẹ̀ |