Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 99 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿لَوۡ كَانَ هَٰٓؤُلَآءِ ءَالِهَةٗ مَّا وَرَدُوهَاۖ وَكُلّٞ فِيهَا خَٰلِدُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 99]
﴿لو كان هؤلاء آلهة ما وردوها وكل فيها خالدون﴾ [الأنبيَاء: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ó bá jẹ́ pé àwọn wọ̀nyí ni ọlọ́hun ni, wọn ìbá tí wọ inú Iná. Olùṣegbére sì ni ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn nínú rẹ̀ |