Quran with Yoruba translation - Surah Al-hajj ayat 10 - الحج - Page - Juz 17
﴿ذَٰلِكَ بِمَا قَدَّمَتۡ يَدَاكَ وَأَنَّ ٱللَّهَ لَيۡسَ بِظَلَّٰمٖ لِّلۡعَبِيدِ ﴾
[الحج: 10]
﴿ذلك بما قدمت يداك وأن الله ليس بظلام للعبيد﴾ [الحج: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn nítorí ohun tí ọwọ́ rẹ̀ tì síwájú. Dájúdájú Allāhu kò níí ṣàbòsí sí àwọn ẹrúsìn Rẹ̀ |