Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 102 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿فَمَن ثَقُلَتۡ مَوَٰزِينُهُۥ فَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡمُفۡلِحُونَ ﴾
[المؤمنُون: 102]
﴿فمن ثقلت موازينه فأولئك هم المفلحون﴾ [المؤمنُون: 102]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá tẹ̀wọ̀n, àwọn wọ̀nyẹn ni olùjèrè |