Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 12 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿وَلَقَدۡ خَلَقۡنَا ٱلۡإِنسَٰنَ مِن سُلَٰلَةٖ مِّن طِينٖ ﴾
[المؤمنُون: 12]
﴿ولقد خلقنا الإنسان من سلالة من طين﴾ [المؤمنُون: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti ṣe ẹ̀dá ènìyàn láti inú ohun tí A mọ jáde láti inú erùpẹ̀ amọ̀ |