Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 13 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿ثُمَّ جَعَلۡنَٰهُ نُطۡفَةٗ فِي قَرَارٖ مَّكِينٖ ﴾
[المؤمنُون: 13]
﴿ثم جعلناه نطفة في قرار مكين﴾ [المؤمنُون: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, A ṣe é ní àtọ̀ sínú àyè ààbò (ìyẹn, ilé-ọmọ) |