Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 16 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿ثُمَّ إِنَّكُمۡ يَوۡمَ ٱلۡقِيَٰمَةِ تُبۡعَثُونَ ﴾
[المؤمنُون: 16]
﴿ثم إنكم يوم القيامة تبعثون﴾ [المؤمنُون: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, dájúdájú ní Ọjọ́ Àjíǹde Wọ́n máa gbe yín dìde |