Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 17 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿وَلَقَدۡ خَلَقۡنَا فَوۡقَكُمۡ سَبۡعَ طَرَآئِقَ وَمَا كُنَّا عَنِ ٱلۡخَلۡقِ غَٰفِلِينَ ﴾
[المؤمنُون: 17]
﴿ولقد خلقنا فوقكم سبع طرائق وما كنا عن الخلق غافلين﴾ [المؤمنُون: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A dá àwọn sánmọ̀ méje sí òkè yín. Àwa kò sì níí dágunlá sí àwọn ẹ̀dá |