Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 65 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿لَا تَجۡـَٔرُواْ ٱلۡيَوۡمَۖ إِنَّكُم مِّنَّا لَا تُنصَرُونَ ﴾
[المؤمنُون: 65]
﴿لا تجأروا اليوم إنكم منا لا تنصرون﴾ [المؤمنُون: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ má kèé gbàjarì lónìí. Dájúdájú kò sí ẹni tí ó máa ràn yín lọ́wọ́ lọ́dọ̀ Wa |