Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 7 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿فَمَنِ ٱبۡتَغَىٰ وَرَآءَ ذَٰلِكَ فَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡعَادُونَ ﴾
[المؤمنُون: 7]
﴿فمن ابتغى وراء ذلك فأولئك هم العادون﴾ [المؤمنُون: 7]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá wá òmíràn (súnmọ́) lẹ́yìn ìyẹn, àwọn wọ̀nyẹn ni àwọn olùtayọ ẹnu-àlà |