Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 74 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿وَإِنَّ ٱلَّذِينَ لَا يُؤۡمِنُونَ بِٱلۡأٓخِرَةِ عَنِ ٱلصِّرَٰطِ لَنَٰكِبُونَ ﴾
[المؤمنُون: 74]
﴿وإن الذين لا يؤمنون بالآخرة عن الصراط لناكبون﴾ [المؤمنُون: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn tí kò sì gba Ọjọ́ Ìkẹ́yìn gbọ́ ni wọ́n ń ṣẹ́rí kúrò lójú ọ̀nà náà |