Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 99 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿حَتَّىٰٓ إِذَا جَآءَ أَحَدَهُمُ ٱلۡمَوۡتُ قَالَ رَبِّ ٱرۡجِعُونِ ﴾
[المؤمنُون: 99]
﴿حتى إذا جاء أحدهم الموت قال رب ارجعون﴾ [المؤمنُون: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Wọ́n ń ṣẹ̀mí lọ) títí di ìgbà tí ikú fi máa dé bá ọ̀kan nínú wọn. Ó sì máa wí pé: “Olúwa mi, Ẹ dá mi padà (sílé ayé) |