Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 38 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَعَادٗا وَثَمُودَاْ وَأَصۡحَٰبَ ٱلرَّسِّ وَقُرُونَۢا بَيۡنَ ذَٰلِكَ كَثِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 38]
﴿وعادا وثمود وأصحاب الرس وقرونا بين ذلك كثيرا﴾ [الفُرقَان: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) àwọn ìjọ ‘Ād, ìjọ Thamūd, ìjọ Rass àti àwọn ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìran mìíràn (t’ó ń bẹ) láààrin wọn |