Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 17 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿أَنۡ أَرۡسِلۡ مَعَنَا بَنِيٓ إِسۡرَٰٓءِيلَ ﴾
[الشعراء: 17]
﴿أن أرسل معنا بني إسرائيل﴾ [الشعراء: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (À ń sọ fún ọ) pé kí o jẹ́ kí àwọn ọmọ ’Isrọ̄’īl máa bá wa lọ |