Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 18 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ أَلَمۡ نُرَبِّكَ فِينَا وَلِيدٗا وَلَبِثۡتَ فِينَا مِنۡ عُمُرِكَ سِنِينَ ﴾
[الشعراء: 18]
﴿قال ألم نربك فينا وليدا ولبثت فينا من عمرك سنين﴾ [الشعراء: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Ṣé kì í ṣe ní ààrin wa ni a ti tọ́ ọ ní kékeré ni, tí o sì gbé ní ọ̀dọ̀ wa fún ọdún púpọ̀ nínú ìṣẹ̀mí ayé rẹ |