Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 16 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَأۡتِيَا فِرۡعَوۡنَ فَقُولَآ إِنَّا رَسُولُ رَبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[الشعراء: 16]
﴿فأتيا فرعون فقولا إنا رسول رب العالمين﴾ [الشعراء: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin méjèèjì, ẹ lọ bá Fir‘aon. Kí ẹ sọ fún un pé: 'Dájúdájú àwa ni Òjíṣẹ́ Olúwa gbogbo ẹ̀dá |