Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 187 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَأَسۡقِطۡ عَلَيۡنَا كِسَفٗا مِّنَ ٱلسَّمَآءِ إِن كُنتَ مِنَ ٱلصَّٰدِقِينَ ﴾
[الشعراء: 187]
﴿فأسقط علينا كسفا من السماء إن كنت من الصادقين﴾ [الشعراء: 187]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, jẹ́ kí apá kan nínú sánmọ̀ ya lù wá mọ́lẹ̀, tí o bá wà nínú àwọn olódodo.” |