Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 186 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَمَآ أَنتَ إِلَّا بَشَرٞ مِّثۡلُنَا وَإِن نَّظُنُّكَ لَمِنَ ٱلۡكَٰذِبِينَ ﴾
[الشعراء: 186]
﴿وما أنت إلا بشر مثلنا وإن نظنك لمن الكاذبين﴾ [الشعراء: 186]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ kò sì jẹ́ kiní kan bí kò ṣe abara bí irú wa. Àti pé a ò rò ọ́ sí kiní kan bí kò ṣe pé ó wà nínú àwọn òpùrọ́ |