Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 212 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿إِنَّهُمۡ عَنِ ٱلسَّمۡعِ لَمَعۡزُولُونَ ﴾
[الشعراء: 212]
﴿إنهم عن السمع لمعزولون﴾ [الشعراء: 212]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti mú wọn takété sí gbígbọ́ rẹ̀ (láti ojú sánmọ̀) |