Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 213 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَلَا تَدۡعُ مَعَ ٱللَّهِ إِلَٰهًا ءَاخَرَ فَتَكُونَ مِنَ ٱلۡمُعَذَّبِينَ ﴾
[الشعراء: 213]
﴿فلا تدع مع الله إلها آخر فتكون من المعذبين﴾ [الشعراء: 213]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, má ṣe pe ọlọ́hun mìíràn mọ́ Allāhu, nítorí kí ìwọ má baà wà nínú àwọn tí A máa jẹ níyà |