Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 215 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَٱخۡفِضۡ جَنَاحَكَ لِمَنِ ٱتَّبَعَكَ مِنَ ٱلۡمُؤۡمِنِينَ ﴾
[الشعراء: 215]
﴿واخفض جناحك لمن اتبعك من المؤمنين﴾ [الشعراء: 215]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí o sì rẹ apá rẹ nílẹ̀ fún àwọn t’ó tẹ̀lé ọ nínú àwọn onígbàgbọ́ òdodo |