Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 216 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿فَإِنۡ عَصَوۡكَ فَقُلۡ إِنِّي بَرِيٓءٞ مِّمَّا تَعۡمَلُونَ ﴾
[الشعراء: 216]
﴿فإن عصوك فقل إني بريء مما تعملون﴾ [الشعراء: 216]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí wọ́n bá sì yapa (àṣẹ) rẹ, sọ pé: “Dájúdájú èmi yọwọ́ yọsẹ̀ nínú ohun tí ẹ̀ ń ṣe (níṣẹ́ aburú).” |