Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 83 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿رَبِّ هَبۡ لِي حُكۡمٗا وَأَلۡحِقۡنِي بِٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[الشعراء: 83]
﴿رب هب لي حكما وألحقني بالصالحين﴾ [الشعراء: 83]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa mi, ta mí ní ọrẹ ipò Ànábì. Dà mí pọ̀ mọ́ àwọn ẹni rere |