Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 35 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿وَإِنِّي مُرۡسِلَةٌ إِلَيۡهِم بِهَدِيَّةٖ فَنَاظِرَةُۢ بِمَ يَرۡجِعُ ٱلۡمُرۡسَلُونَ ﴾
[النَّمل: 35]
﴿وإني مرسلة إليهم بهدية فناظرة بم يرجع المرسلون﴾ [النَّمل: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú mo máa fi ẹ̀bùn kan ránṣẹ́ sí wọn. Mo sì máa wòye sí ohun tí àwọn ìránṣẹ́ yóò mú padà (ní èsì).” |