Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 43 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿وَصَدَّهَا مَا كَانَت تَّعۡبُدُ مِن دُونِ ٱللَّهِۖ إِنَّهَا كَانَتۡ مِن قَوۡمٖ كَٰفِرِينَ ﴾
[النَّمل: 43]
﴿وصدها ما كانت تعبد من دون الله إنها كانت من قوم كافرين﴾ [النَّمل: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ohun t’ó ń jọ́sìn fún lẹ́yìn Allāhu sì ṣẹ́rí rẹ̀ (kúrò níbi ìjọ́sìn fún Allāhu). Dájúdájú ó wà nínú ìjọ aláìgbàgbọ́ |