Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 73 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿وَإِنَّ رَبَّكَ لَذُو فَضۡلٍ عَلَى ٱلنَّاسِ وَلَٰكِنَّ أَكۡثَرَهُمۡ لَا يَشۡكُرُونَ ﴾
[النَّمل: 73]
﴿وإن ربك لذو فضل على الناس ولكن أكثرهم لا يشكرون﴾ [النَّمل: 73]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Olúwa rẹ mà ni Ọlọ́lá lórí àwọn ènìyàn, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn kì í dúpẹ́ (fún Un) |