Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 67 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿فَأَمَّا مَن تَابَ وَءَامَنَ وَعَمِلَ صَٰلِحٗا فَعَسَىٰٓ أَن يَكُونَ مِنَ ٱلۡمُفۡلِحِينَ ﴾
[القَصَص: 67]
﴿فأما من تاب وآمن وعمل صالحا فعسى أن يكون من المفلحين﴾ [القَصَص: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n ní ti ẹni tí ó bá ronú pìwàdà, tí ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí ó sì ṣe iṣẹ́ rere, ó súnmọ́ pé ó máa wà nínú àwọn olùjèrè |