Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 6 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿هُوَ ٱلَّذِي يُصَوِّرُكُمۡ فِي ٱلۡأَرۡحَامِ كَيۡفَ يَشَآءُۚ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡحَكِيمُ ﴾
[آل عِمران: 6]
﴿هو الذي يصوركم في الأرحام كيف يشاء لا إله إلا هو العزيز﴾ [آل عِمران: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òun ni Ẹni tí Ó ń yàwòrán yín sínú àpòlùkẹ́ bí Ó ṣe fẹ́. Kò sí ọlọ́hun kan tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun, Alágbára Ọlọ́gbọ́n |