Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 70 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿يَٰٓأَهۡلَ ٱلۡكِتَٰبِ لِمَ تَكۡفُرُونَ بِـَٔايَٰتِ ٱللَّهِ وَأَنتُمۡ تَشۡهَدُونَ ﴾
[آل عِمران: 70]
﴿ياأهل الكتاب لم تكفرون بآيات الله وأنتم تشهدون﴾ [آل عِمران: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ahlul-kitāb, nítorí kí ni ẹ óò fi ṣàì gbàgbọ́ nínú àwọn āyah Allāhu, ẹ sì ń jẹ́rìí (sí òdodo rẹ̀) |