Quran with Yoruba translation - Surah Luqman ayat 26 - لُقمَان - Page - Juz 21
﴿لِلَّهِ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۚ إِنَّ ٱللَّهَ هُوَ ٱلۡغَنِيُّ ٱلۡحَمِيدُ ﴾
[لُقمَان: 26]
﴿لله ما في السموات والأرض إن الله هو الغني الحميد﴾ [لُقمَان: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ti Allāhu ni ohunkóhun t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Dájúdájú Allāhu, Òun ni Ọlọ́rọ̀, Ọlọ́pẹ́ |