×

So pe: “Molaika iku eyi ti A fi ti yin maa gba 32:11 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah As-Sajdah ⮕ (32:11) ayat 11 in Yoruba

32:11 Surah As-Sajdah ayat 11 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah As-Sajdah ayat 11 - السَّجدة - Page - Juz 21

﴿۞ قُلۡ يَتَوَفَّىٰكُم مَّلَكُ ٱلۡمَوۡتِ ٱلَّذِي وُكِّلَ بِكُمۡ ثُمَّ إِلَىٰ رَبِّكُمۡ تُرۡجَعُونَ ﴾
[السَّجدة: 11]

So pe: “Molaika iku eyi ti A fi ti yin maa gba emi yin. Leyin naa, odo Oluwa yin ni won maa da yin pada si.” gege bi O se je Eledaa ohun gbogbo. Ko si eda kan ti o maa to isemi wo afi pelu iyonda Allahu (subhanahu wa ta'ala). Ko si si eda kan ti o maa to iku wo afi pelu iyonda Allahu (subhanahu wa ta'ala). Nipa eyi Allahu l’O n fi ase Re gba emi kuro lara eda Re ni akoko ti O ti ko mo on ninu kadara. Iyen ni o jeyo ninu surah az-Zumor; 39:42. Bakan naa

❮ Previous Next ❯

ترجمة: قل يتوفاكم ملك الموت الذي وكل بكم ثم إلى ربكم ترجعون, باللغة اليوربا

﴿قل يتوفاكم ملك الموت الذي وكل بكم ثم إلى ربكم ترجعون﴾ [السَّجدة: 11]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Sọ pé: “Mọlāika ikú èyí tí A fi tì yín máa gba ẹ̀mí yín. Lẹ́yìn náà, ọ̀dọ̀ Olúwa yín ni wọn máa da yín padà sí.” gẹ́gẹ́ bí Ó ṣe jẹ́ Ẹlẹ́dàá ohun gbogbo. Kò sí ẹ̀dá kan tí ó máa tọ́ ìṣẹ̀mí wò àfi pẹ̀lú ìyọ̀ǹda Allāhu (subhānahu wa ta'ālā). Kò sì sí ẹ̀dá kan tí ó máa tọ́ ikú wò àfi pẹ̀lú ìyọ̀ǹda Allāhu (subhānahu wa ta'ālā). Nípa èyí Allāhu l’Ó ń fi àṣẹ Rẹ̀ gba ẹ̀mí kúrò lára ẹ̀dá Rẹ̀ ní àkókò tí Ó ti kọ mọ́ ọn nínú kádàrá. Ìyẹn ni ó jẹyọ nínú sūrah az-Zumọr; 39:42. Bákan náà
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek