Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ahzab ayat 68 - الأحزَاب - Page - Juz 22
﴿رَبَّنَآ ءَاتِهِمۡ ضِعۡفَيۡنِ مِنَ ٱلۡعَذَابِ وَٱلۡعَنۡهُمۡ لَعۡنٗا كَبِيرٗا ﴾
[الأحزَاب: 68]
﴿ربنا آتهم ضعفين من العذاب والعنهم لعنا كبيرا﴾ [الأحزَاب: 68]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa wa! Fún wọn ní ìlọ́po méjì nínú ìyà. Kí O sì ṣẹ́bi lé wọn ní ìṣẹ́bi t’ó tóbi.” |