Quran with Yoruba translation - Surah FaTir ayat 15 - فَاطِر - Page - Juz 22
﴿۞ يَٰٓأَيُّهَا ٱلنَّاسُ أَنتُمُ ٱلۡفُقَرَآءُ إِلَى ٱللَّهِۖ وَٱللَّهُ هُوَ ٱلۡغَنِيُّ ٱلۡحَمِيدُ ﴾
[فَاطِر: 15]
﴿ياأيها الناس أنتم الفقراء إلى الله والله هو الغني الحميد﴾ [فَاطِر: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ènìyàn, ẹ̀yin ni aláìní (tí ẹ ní bùkátà) sí Allāhu. Allāhu, Òun ni Ọlọ́rọ̀, Ọlọ́pẹ́ |