Quran with Yoruba translation - Surah FaTir ayat 43 - فَاطِر - Page - Juz 22
﴿ٱسۡتِكۡبَارٗا فِي ٱلۡأَرۡضِ وَمَكۡرَ ٱلسَّيِّيِٕۚ وَلَا يَحِيقُ ٱلۡمَكۡرُ ٱلسَّيِّئُ إِلَّا بِأَهۡلِهِۦۚ فَهَلۡ يَنظُرُونَ إِلَّا سُنَّتَ ٱلۡأَوَّلِينَۚ فَلَن تَجِدَ لِسُنَّتِ ٱللَّهِ تَبۡدِيلٗاۖ وَلَن تَجِدَ لِسُنَّتِ ٱللَّهِ تَحۡوِيلًا ﴾
[فَاطِر: 43]
﴿استكبارا في الأرض ومكر السيئ ولا يحيق المكر السيئ إلا بأهله فهل﴾ [فَاطِر: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ní ti ṣíṣe ìgbéraga lórí ilẹ̀ àti ní ti ìpète aburú. Ìyà ìpète aburú kò sì níí kò lé ẹnì kan lórí àfi oníṣẹ́ aburú. Ṣé wọ́n ń retí kiní kan bí kò ṣe ìṣe (Allāhu lórí) àwọn ẹni àkọ́kọ́? Nítorí náà, o ò níí rí ìyípadà fún ìṣe Allāhu. Àní sẹ́, o ò níí rí ìyípadà fún ìṣe Allāhu |