Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 27 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿بِمَا غَفَرَ لِي رَبِّي وَجَعَلَنِي مِنَ ٱلۡمُكۡرَمِينَ ﴾
[يسٓ: 27]
﴿بما غفر لي ربي وجعلني من المكرمين﴾ [يسٓ: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nípa bí Olúwa mi ṣe foríjìn mí àti (bí) Ó ṣe fi mí sí ara àwọn alápọ̀n-ọ́nlé (wọn ìbá ronú pìwàdà).” |