Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 28 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿۞ وَمَآ أَنزَلۡنَا عَلَىٰ قَوۡمِهِۦ مِنۢ بَعۡدِهِۦ مِن جُندٖ مِّنَ ٱلسَّمَآءِ وَمَا كُنَّا مُنزِلِينَ ﴾
[يسٓ: 28]
﴿وما أنـزلنا على قومه من بعده من جند من السماء وما كنا﴾ [يسٓ: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò sọ ọmọ ogun kan kalẹ̀ lé àwọn ènìyàn rẹ̀ lórí láti sánmọ̀ lẹ́yìn rẹ̀. A ò sì sọ (mọlāika kan) kalẹ̀ (fún ìparun wọn) |