Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 34 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَجَعَلۡنَا فِيهَا جَنَّٰتٖ مِّن نَّخِيلٖ وَأَعۡنَٰبٖ وَفَجَّرۡنَا فِيهَا مِنَ ٱلۡعُيُونِ ﴾
[يسٓ: 34]
﴿وجعلنا فيها جنات من نخيل وأعناب وفجرنا فيها من العيون﴾ [يسٓ: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A tún ṣe àwọn ọgbà dàbínù àti àjàrà sínú ilẹ̀. A sì mú àwọn odò ìṣẹ́lẹ̀rú ṣẹ́ yọ láti inú rẹ̀ |