Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 41 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَءَايَةٞ لَّهُمۡ أَنَّا حَمَلۡنَا ذُرِّيَّتَهُمۡ فِي ٱلۡفُلۡكِ ٱلۡمَشۡحُونِ ﴾
[يسٓ: 41]
﴿وآية لهم أنا حملنا ذريتهم في الفلك المشحون﴾ [يسٓ: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó tún jẹ́ àmì fún wọn pé dájúdájú Àwa gbé àwọn àrọ́mọdọ́mọ wọn gun ọkọ̀ ojú-omi t’ó kún kẹ́kẹ́ |