Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 40 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿لَا ٱلشَّمۡسُ يَنۢبَغِي لَهَآ أَن تُدۡرِكَ ٱلۡقَمَرَ وَلَا ٱلَّيۡلُ سَابِقُ ٱلنَّهَارِۚ وَكُلّٞ فِي فَلَكٖ يَسۡبَحُونَ ﴾
[يسٓ: 40]
﴿لا الشمس ينبغي لها أن تدرك القمر ولا الليل سابق النهار وكل﴾ [يسٓ: 40]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò yẹ fún òòrùn láti lo àsìkò òṣùpá. Kò sì yẹ fún alẹ́ láti lo àsìkò ọ̀sán. Ìkọ̀ọ̀kan wà ní òpópónà róbótó t’ó ń tọ̀ |