Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 60 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿۞ أَلَمۡ أَعۡهَدۡ إِلَيۡكُمۡ يَٰبَنِيٓ ءَادَمَ أَن لَّا تَعۡبُدُواْ ٱلشَّيۡطَٰنَۖ إِنَّهُۥ لَكُمۡ عَدُوّٞ مُّبِينٞ ﴾
[يسٓ: 60]
﴿ألم أعهد إليكم يابني آدم أن لا تعبدوا الشيطان إنه لكم عدو﴾ [يسٓ: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ọmọ (Ànábì) Ādam, ṣe Èmi kò ti pa yín ní àṣẹ pé kí ẹ má ṣe jọ́sìn fún Èṣù? Dájúdájú òun ni ọ̀tá pọ́nńbélé fun yín |