Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 68 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَمَن نُّعَمِّرۡهُ نُنَكِّسۡهُ فِي ٱلۡخَلۡقِۚ أَفَلَا يَعۡقِلُونَ ﴾
[يسٓ: 68]
﴿ومن نعمره ننكسه في الخلق أفلا يعقلون﴾ [يسٓ: 68]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí A bá fún ní ẹ̀mí gígùn lò, A óò sọ ẹ̀dá rẹ̀ di ọ̀lẹ, ṣé wọn kò níí ṣe làákàyè ni |