Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 70 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿لِّيُنذِرَ مَن كَانَ حَيّٗا وَيَحِقَّ ٱلۡقَوۡلُ عَلَى ٱلۡكَٰفِرِينَ ﴾
[يسٓ: 70]
﴿لينذر من كان حيا ويحق القول على الكافرين﴾ [يسٓ: 70]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí kí ó lè ṣèkìlọ̀ fún ẹni tí ó jẹ́ alààyè àti nítorí kí ọ̀rọ̀ náà lè kò lórí àwọn aláìgbàgbọ́ |