Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 140 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿إِذۡ أَبَقَ إِلَى ٱلۡفُلۡكِ ٱلۡمَشۡحُونِ ﴾
[الصَّافَات: 140]
﴿إذ أبق إلى الفلك المشحون﴾ [الصَّافَات: 140]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹ rántí) nígbà tí ó sá lọ sínú ọkọ̀ ojú-omi t’ó kún kẹ́kẹ́ |