Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 143 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿فَلَوۡلَآ أَنَّهُۥ كَانَ مِنَ ٱلۡمُسَبِّحِينَ ﴾
[الصَّافَات: 143]
﴿فلولا أنه كان من المسبحين﴾ [الصَّافَات: 143]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, tí kò bá jẹ́ pé ó wà nínú àwọn olùṣàfọ̀mọ́ fún Allāhu |