Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 145 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿۞ فَنَبَذۡنَٰهُ بِٱلۡعَرَآءِ وَهُوَ سَقِيمٞ ﴾
[الصَّافَات: 145]
﴿فنبذناه بالعراء وهو سقيم﴾ [الصَّافَات: 145]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A jù ú sí orí ilẹ́ gban̄sasa létí omi. Ó sì jẹ́ aláìlera |