Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 168 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿لَوۡ أَنَّ عِندَنَا ذِكۡرٗا مِّنَ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[الصَّافَات: 168]
﴿لو أن عندنا ذكرا من الأولين﴾ [الصَّافَات: 168]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ó bá jẹ́ pé dájúdájú a bá ní (tírà) ìrántí kan nínú (àwọn tírà) àwọn ẹni àkọ́kọ́ |