Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 5 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿رَّبُّ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَمَا بَيۡنَهُمَا وَرَبُّ ٱلۡمَشَٰرِقِ ﴾
[الصَّافَات: 5]
﴿رب السموات والأرض وما بينهما ورب المشارق﴾ [الصَّافَات: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àti ohunkóhun tí ń bẹ láààrin àwọn méjèèjì. Òun sì ni Olúwa àwọn ibùyọ òòrùn |