Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 53 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿أَءِذَا مِتۡنَا وَكُنَّا تُرَابٗا وَعِظَٰمًا أَءِنَّا لَمَدِينُونَ ﴾
[الصَّافَات: 53]
﴿أئذا متنا وكنا ترابا وعظاما أئنا لمدينون﴾ [الصَّافَات: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé nígbà tí a bá kú tán, tí a ti di erùpẹ̀ àti egungun, ṣé dájúdájú Wọn yóò san wá ní ẹ̀san ni?” |