Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 12 - صٓ - Page - Juz 23
﴿كَذَّبَتۡ قَبۡلَهُمۡ قَوۡمُ نُوحٖ وَعَادٞ وَفِرۡعَوۡنُ ذُو ٱلۡأَوۡتَادِ ﴾
[صٓ: 12]
﴿كذبت قبلهم قوم نوح وعاد وفرعون ذو الأوتاد﴾ [صٓ: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ìjọ Nūh, ìjọ ‘Ād àti Fir‘aon, eléèkàn, wọ́n pe òdodo nírọ́ ṣíwájú wọn |